Hymn 927 – E wa k’a jo jumo korin | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "E wa k’a jo jumo korin" (C&S Hymn #927, Yoruba). 1. E wa k’a jo jumo korin Ife ni Olorun Orun, aye mu yin won wa Ife…

Hymn 927 – E wa k’a jo jumo korin | C&S Yoruba Hymnary
1. E wa k’a jo jumo korin Ife ni Olorun Orun, aye mu yin won wa Ife ni Olorun Ki gbogbo okan ji kuro Ninu ese ki won f’ayo Korin didun n’tori Jesu lfe ni Olorun. 2. E so ni gbogbo agbaye Ife ni Olorun N’nu Krist’ l’ekun ‘rapada wa Ife ni Olorun Eje Re le w’ese wa nu Emi Re s’oru wa d’osan O nto ‘kan wa lati so pe Ife ni Olorun. 3. Ayo ni ipin wa nihin Ife ni Olorun Okan wa nyo si ‘leri Re Ife ni Olorun Orun at’ abo wa losan O si mba wa gbe ni oru On yo wa pelu wa titi Ife ni Olorun. 4. Ni Sion Iao tun korin yi Ife ni Olorun Orin t’o ga soke julo Ife ni Olorun Titi aye aninipekun Pelu awon mimo loke Orin wa to dun julo ni Ife ni Olorun. Amin

Hymn 927 – E wa k’a jo jumo korin | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia