Hymn 912 – AWON omode s’eka wewe | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "AWON omode s’eka wewe" (C&S Hymn #912, Yoruba). 1. AWON omode s’eka wewe at’imope s'ona Won si nke, Hosana Eyi ni orin…

Hymn 912 – AWON omode s’eka wewe | C&S Yoruba Hymnary
1. AWON omode s’eka wewe at’imope s'ona Won si nke, Hosana Eyi ni orin segun t’a ko wonu Jerusalem Hosana! Hosana! Egbe: Eyi l'Omo nla Dafidi ati Oba Israeli Ogun ketekete lo fun igbala omo eniyan Hosana! Hosana! Hosana si Omo Dafidi. 2. Awon agbagba gbiyanju lati pa won lenu mo Won tun nke Hosana B‘awon wonyi pa enu won mo okuta yo soro Hosana! Hosana! Egbe: Eyi l'Omo nla... 3. E so fun omo binrin Sion pe Oba re mbo wa Hosana! Hosana! O tenu, O si joko lori omo Ketekete Hosana! Hosana! Egbe: Eyi l'Omo nla... 4. Olubukun I’Eni ti mbo wa l‘oruko Oluwa Hosana! Hosana! E te okan yin si ona fun Kristi Oba Ogo Hosana! Hosana! Egbe: Eyi l'Omo nla Dafidi ati Oba Israeli Ogun ketekete lo fun igbala omo eniyan Hosana! Hosana! Hosana si Omo Dafidi. Amin

Hymn 912 – AWON omode s’eka wewe | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia