Hymn 911 – MO layo pe Baba wa li orun | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "MO layo pe Baba wa li orun" (C&S Hymn #911, Yoruba). 1. MO layo pe Baba wa li orun F'ife Re han ninu iwe li orun Mo…

Hymn 911 – MO layo pe Baba wa li orun | C&S Yoruba Hymnary
1. MO layo pe Baba wa li orun F'ife Re han ninu iwe li orun Mo r'ohun ‘yanu ninu Bibeli Ife Jesu si mi b’o ti po to. Egbe: Mo layo wipe Jesu fe mi Jesu fe mi, Jesu fe mi Mo Iayo wipe Jesu fe mi Jesu fe an'emi. 2. Mo gbagbe Re, mo si sako kuro Sibe o fe mi, bi mo ti nsako Mo fo pada s’abe apa ‘fe Re Gbati mo ranti pe Jesu fe mi. Egbe: Mo layo wipe Jesu fe mi... 3. B‘o je pe orin kan ni mo le ko Ninu ewa ni mo r‘Oba Nla ni Eyi ni y’o j'orin mi tit‘aye Iyanu lo je pe Jesu fe mi. Egbe: Mo layo wipe Jesu fe mi... 4. Jesu fe mi, mo mo pe, emi fe E lfe lo mu wa lati gba mi la N'ife l’O ku lori agbelebu O da mi loju pe Jesu fe mi. Egbe: Mo layo wipe Jesu fe mi... 5. B’a bi mi lere, kini esi mi? Ogo fun Jesu, eyi si daju Erni mimo pelu mi si gbagbo Lati jeri wipe Jesu fe mi. Egbe: Mo layo wipe Jesu fe mi... 6. Eyi daju pe, mo ni isimi A bukun mi pe mo gba Jesu gbo A gb’okan mi la, Esu sa fun mi Gbati mo so fun u pe Jesu fe mi. Egbe: Mo layo wipe Jesu fe mi Jesu fe mi, Jesu fe mi Mo Iayo wipe Jesu fe mi Jesu fe an'emi. Amin

Hymn 911 – MO layo pe Baba wa li orun | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia