Hymn 903 – LATI 'nu ide ibanuje | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "LATI 'nu ide ibanuje" (C&S Hymn #903, Yoruba). 1. LATI 'nu ide ibanuje Jesu mo de, Jesu mo de Mo wa gba omnira at’ayo…
1. LATI 'nu ide ibanuje Jesu mo de, Jesu mo de Mo wa gba omnira at’ayo Jesu mo wa do Re Alaisan, emi nfe iwosan Alaini, so mi di oloro Elese, mo wa si odo Re Jesu, mo wa‘do Re. 2. Eni-tiju ati eIeya Jesu mo de, Jesu mo de Mo wa jere nla n’nu iku Re Jesu mo wa’do Re Wo n'itunu fun ibanuje Wo n‘isimi fun gbogbo iji Jesu mo wa’do Re. 3. Ninu rudurudu aiye yi Jesu mo de, Jesu mo de Mo wa s'inu pipe ife Re Jesu mo wa’do Re Mu mi kuro n’nu ife ara Kuro ninu aiye asan yi Ki nle wa fi’ye idi goke Jesu mo wa’do Re. 4. N‘nu eru iku at‘iboji Jesu mo de, Jesu mo de Mo wa s'inu ayo ile mi Jesu mo wa'do Re Lati nu iho iparun nla Sinu alafia t‘o jinle Lati wa w‘oju Re ologo Jesu mo wa‘do Re. Amin
Hymn 903 – LATI 'nu ide ibanuje | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia