Hymn 900 – OJO nla kan n bO wa | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "OJO nla kan n bO wa" (C&S Hymn #900, Yoruba). 1. OJO nla kan n bO wa Ojo nla kan n bo Ojo nla kan bo wa nigboose…

Hymn 900 – OJO nla kan n bO wa | C&S Yoruba Hymnary
1. OJO nla kan n bO wa Ojo nla kan n bo Ojo nla kan bo wa nigboose T’awon eniyan mimo at'elese yoo pinya lwo ha setan fun ojo naa. Egbe: O ha setan? O ha setan O ha setan fun ojo 'daju O ha setan? O ha setan Fun ojo nla naa. 2. Ojo didan kan n be Ojo naa n bo wa Ojo didan kan n bo nigbaoose Sugbon didan re je ti awon t'o fe Oluwa lwo ha setan fun ojo naa. Egbe: O ha setan? O ha setan... 3. Ojo ‘banuje n bo Ojo naa n bo wa Ojo ‘banuje n bo nigboose T’elese yio gbo pe, E to, Emi ko mo yin ri Iwo ha setan fun ojo naa. Egbe: O ha setan? O ha setan O ha setan fun ojo 'daju O ha setan? O ha setan Fun ojo nla naa. Amin

Hymn 900 – OJO nla kan n bO wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia