Hymn 899 – Gba ti ipe Oluwa ba dun t‘aye yoo | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Gba ti ipe Oluwa ba dun t‘aye yoo" (C&S Hymn #899, Yoruba). 1. Gba ti ipe Oluwa ba dun t‘aye yoo si fo lo Ti imole ojo…
1. Gba ti ipe Oluwa ba dun t‘aye yoo si fo lo Ti imole ojo titun yoo si de Nigba ti awon omo igbala ba pejo l'oke T’a ba si p‘oruko lohun, n o wa n’be. Egbe: Gba t'a ba p’oruko lohun Gba t'a ba p’oruko Iohun Gba t'a ba p'oruko lohun Gba t’a ba p'oruko Iohun n o wa n’be. 2. L'ooro ayo naa t‘awon oku n‘nu Kristi yoo jide Ti won yoo si pin n‘nu ogo ajinde Gba ti awon ayanfe yoo pejo si oke orun T‘a ba si p‘oruko l‘ohun, n o wa n'be. Egbe: Gba t'a ba p'oruko lohun... 3. Je ki a fi gbogbo akoko wa s'ise f'Oluwa. Jeki a rohin ife iyanu Re Nigba ti a ba si pari ire-ije wa l’aye T'a ba si p’oruko l’ohun, n o wa n'be Egbe: Gba t'a ba p’oruko lohun Gba t'a ba p’oruko Iohun Gba t'a ba p'oruko lohun Gba t’a ba p'oruko Iohun n o wa n’be. Amin
Hymn 899 – Gba ti ipe Oluwa ba dun t‘aye yoo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia