Hymn 891 – ORE-OFE Baba, ati t‘Omo Re | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "ORE-OFE Baba, ati t‘Omo Re" (C&S Hymn #891, Yoruba). 1. ORE-OFE Baba, ati t‘Omo Re Ore-ofe Emi, metalokan lai My iyin…
1. ORE-OFE Baba, ati t‘Omo Re Ore-ofe Emi, metalokan lai My iyin wa funwa ati imole O le okunkun lo, o nm‘okan wa yo. Egbe: Ore-Ofe Olorun si wa iyanu ni Ope ore-ofe Re wa nibi gbogbo Ore-ofe nla ti' nfo gbogbo eda mo Wa to ebun ofe wo, ore-ofe nla. 2. Nibiti ese po, or'ofe njoba Itan ‘yanu l‘eyi, to sowon pupo Mase so ‘reti nu, ore‐ofe nsan O ga ju orun lo, o jin ju okun. 3. A nf‘ ore-ore yi, lo gbogb’enia We, iwo t'eru, y’o gbe won fun Enika to wa, a ki y’o tanu Yio fe o lofe, ma siyemeji. Amin
Hymn 891 – ORE-OFE Baba, ati t‘Omo Re | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia