Hymn xvi – Wa! Wa ba wa gbe O | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Wa! Wa ba wa gbe O" (C&S Hymn #xvi, Yoruba). Wa! Wa ba wa gbe O ) 2ce Ninu ile Rẹ Oluwa ) Awa n jọsin a tun n sọpe Ọpẹ…

Hymn xvi – Wa! Wa ba wa gbe O | C&S Yoruba Hymnary
Wa! Wa ba wa gbe O ) 2ce Ninu ile Rẹ Oluwa ) Awa n jọsin a tun n sọpe Ọpẹ ore o Eleti gbaroye gbọ o Ọba oke mi si wa o (2ce) Pawa mọ lọwọ tẹmbẹlẹkun inu aye Ka se 'fẹ Oluwa b'awọn ara igbani Ọba to gbọ ti Mose Wa gbọ tiwa Oluwa ASẸ, AMIN O KO SẸ.

Hymn xvi – Wa! Wa ba wa gbe O | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia