Hymn xiv – Oluwa awa de, kabiyesi Oba wa | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Oluwa awa de, kabiyesi Oba wa" (C&S Hymn #xiv, Yoruba). Oluwa awa de, kabiyesi Ọba wa Ẹlẹru ni yin, dariji wa Baba wa…
Oluwa awa de, kabiyesi Ọba wa Ẹlẹru ni yin, dariji wa Baba wa Ta l'a ni t'a gbojule Ta la ni ta fẹhin ti, Bikose Iwọ Ọlọrun wa, Ẹlẹru ni yin dariji wa o. ASẸ
Hymn xiv – Oluwa awa de, kabiyesi Oba wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia