Hymn xiii – Olorun Baba wa | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Olorun Baba wa" (C&S Hymn #xiii, Yoruba). Ọlọrun Baba wa, Masai wa sarin F'ara han wa Ka sin Ọ bo ti tọ Ka sin Ọ bo ti…

Hymn xiii – Olorun Baba wa | C&S Yoruba Hymnary
Ọlọrun Baba wa, Masai wa sarin F'ara han wa Ka sin Ọ bo ti tọ Ka sin Ọ bo ti yẹ Jẹ ki'sin wa le jẹ Isin ọwọ. AMIN

Hymn xiii – Olorun Baba wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia