Hymn 876 – YIN Oluwa, enyin mimo | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "YIN Oluwa, enyin mimo" (C&S Hymn #876, Yoruba). 1. YIN Oluwa, enyin mimo Awa ti je ni ‘gbese to? Je k'a mu gbogbo ini…
1. YIN Oluwa, enyin mimo Awa ti je ni ‘gbese to? Je k'a mu gbogbo ini wa Wa pelu ayo. 2. Jesus l'Oko t'o dara ju O nfun wa l'okun l'oju ‘ja lbi kan ko le de ba wa ‘Gbat‘ a gbekele. 3. Gbekele yin le, eyin mimo Olododo l’Olorun wa Ko s'ohun to le, ya awon T‘O fe l‘odo Re. 4. F'ore ofe Re pa wa mo K‘a le tubo faramo O Titi ao fi de ‘nu ogo At‘ ayo l‘orun. 5. ‘Gbana l‘ ao de ibi mimo ‘Gbana l'a o si di mimo Ayo nla ti a ko so Ni y‘o je ti wa. Amin
Hymn 876 – YIN Oluwa, enyin mimo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia