Hymn 875 – Fl iyin fun! Jesu, Olurapada wa | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Fl iyin fun! Jesu, Olurapada wa" (C&S Hymn #875, Yoruba). 1. Fl iyin fun! Jesu, Olurapada wa Ki aiye k'okiki ire Re…
1. Fl iyin fun! Jesu, Olurapada wa Ki aiye k'okiki ire Re nla Fi iyin fun! enyin Angeli ologo F'ola at‘ogo fun oruko Re B'Olusaguntan, Jesu y'o to omo Re L'aoa Re lo ngbe won le lojojo Enyin eniyan mimo ti ngb‘oke Sion Fi iyin fun pelu orin ayo. 2. Fi iyin fun! Jesu, Olurapada wa Fun wa O t‘eje Re sile Oku On ni apata ati reti gbala wa Yin Jesu ti a kan m'agbelebu Olugbala t'o f’ara da irora nla Ti a fi ade egun de lori Eniti a pa nitori awa eda Oba Ogo njoba titi lailai. 3. Fi iyin fun! Jesu, Olurapada wa Ki ariwo iyin gba orun kan Jesu Oluwa njoba ati lai lai Se l’oba gbogb'enyi alagbara Asegun iku, fi yo rohin na ka Isegun re ha da, isa‐oku? Jesu ye! ko tun si wahala fun wa mo Tori O lagbara lati gbala Tori O lagbara lati gbala. Amin
Hymn 875 – Fl iyin fun! Jesu, Olurapada wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia