Hymn 810 – WA, royin Re yika | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "WA, royin Re yika" (C&S Hymn #810, Yoruba). WA, royin Rẹ yika, K'a si kọrin ogo; Alagbara ni Oluwa, Ọba gbogbo ayé.…

Hymn 810 – WA, royin Re yika | C&S Yoruba Hymnary
WA, royin Rẹ yika, K'a si kọrin ogo; Alagbara ni Oluwa, Ọba gbogbo ayé. Oun l'O da 'wọn ibu; O pala fun okun; Tirẹ ni gbogb' awọn odo, At' iyangbẹ ilẹ. Wa, wolẹ n'itẹ Rẹ, Wa, juba Oluwa; Isẹ ọwọ Rẹ l'awa se, Ọrọ Rẹ l'o da wa. Gbo ohun Rẹ loni, Ma si se mu binu; Wa, bi eni ayanfẹ Rẹ, Jẹwọ Ọlọrun rẹ. AMIN

Hymn 810 – WA, royin Re yika | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia