Hymn 807 – LOKE odo Jodani | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "LOKE odo Jodani" (C&S Hymn #807, Yoruba). ―Orin isẹdalẹ Ẹgbẹ Kérúbù ati Séráfù Mimọ ti a da silẹ lati ọwọ Alagba wa,…

Hymn 807 – LOKE odo Jodani | C&S Yoruba Hymnary
―Orin isẹdalẹ Ẹgbẹ Kérúbù ati Séráfù Mimọ ti a da silẹ lati ọwọ Alagba wa, Mose Orimolade. LOKE odo Jọdani L'a n pe mi (2ce) Awọn olufẹ mi to ti lọ, to ti lọ, Mo fẹ lọ ba wọn wọle ogo A ki yo ya mọ titi lailai lai. Wọ sile, wọ sile ifẹ, Iwe Jesu sọ fun mi pe, Angeli gbe mi lọmọ ayọ, Jesu si mu mi wọle e. AMIN

Hymn 807 – LOKE odo Jodani | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia