Hymn 793 – ENI owo, Eni owo | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "ENI owo, Eni owo" (C&S Hymn #793, Yoruba). ẸNI ọwọ, Ẹni ọwọ, ) Ẹni ọwọ, a juba Rẹ o )2ce Ko s'Ọba bi Rẹ o, Oluwa )2…

Hymn 793 – ENI owo, Eni owo | C&S Yoruba Hymnary
ẸNI ọwọ, Ẹni ọwọ, ) Ẹni ọwọ, a juba Rẹ o )2ce Ko s'Ọba bi Rẹ o, Oluwa )2 Ẹni ọwọ, Ẹni ọwọ, Ẹni ọwọ, a juba Rẹ o Olulana, Olulana )2ce Olulana la'na rẹ kan wa o)2 A de lati yin Ọ o, Oluwa)2ce Olulana, Olulana, Olulana, la'na rẹ kan wa o. Olupese, Olupese, )2ce Olupese, pese kari wa o) Ko s'Ọba bi Rẹ o, Oluwa)2 Olupese, Olupese, Olupese, pese kari wa o Alabo, Alabo, )2ce Alabo dabo Rẹ bo wa o )2 Ko s'Ọba bi Rẹ o, Oluwa)2 Alabo, Alabo, Alabo, dabo Rẹ bo wa o. AMIN

Hymn 793 – ENI owo, Eni owo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia