Hymn 673 – GBA T'O ba de gba t'o ba de | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "GBA T'O ba de gba t'o ba de" (C&S Hymn #673, Yoruba). GBA T'O ba de gba t'o ba de, Lati sir' ọsọ Rẹ, Gbogb' ọsọ Rẹ…
GBA T'O ba de gba t'o ba de, Lati sir' ọsọ Rẹ, Gbogb' ọsọ Rẹ iyebiye, Awọn ti o fẹ. Bi irawọ owurọ, wọn n s'ade Rẹ lọsọ, Ẹwa wọn o yọ pupọ, ẹwa f'ade Rẹ. Yio ko jọ, yoo ko jọ, Osọ ijọba Rẹ, Awọn mimọ, awọn didan, Awọn ti o fẹ. Bi irawọ owurọ, wọn n s'ade Rẹ lọsọ, Ẹwa wọn o yọ pupọ, ẹwa f'ade Rẹ. Awọn ewe, awọn ewe, T'o fẹ Olugbala, Ni ọsọ Rẹ iyebiye, Awọn ti o fẹ. Bi irawọ owurọ, wọn n s'ade Rẹ lọsọ, Ẹwa wọn o yọ pupọ, ẹwa f'ade Rẹ. AMIN Bi irawọ owurọ, wọn n s'ade Rẹ lọsọ, Ẹwa wọn o yọ pupọ, ẹwa f'ade Rẹ.
Hymn 673 – GBA T'O ba de gba t'o ba de | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia