Hymn 582 – ORO Alafia | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "ORO Alafia" (C&S Hymn #582, Yoruba). ỌRỌ Alafia, La fi sin yin ara, K'alafia bi odo nla, Ma ba yin gbe. N'nu ọrọ…

Hymn 582 – ORO Alafia | C&S Yoruba Hymnary
ỌRỌ Alafia, La fi sin yin ara, K'alafia bi odo nla, Ma ba yin gbe. N'nu ọrọ adura, A f'awọn ara wa, Ni isọ Oluwa lọwọ, Ọrẹ totọ Ọrọ ifẹ didun, L'a fi p'odigbose, Ifẹ wa ati t'Ọlọrun, Y'o ba wọn gbe. Ọrọ gbagbọ lile, Ni igbẹkẹle wa, Pe, Oluwa y'o se ranwọ, Nigba gbogbo. Ọrọ 'reti didun, Y'o mu Ipinya wa dun, Y'o sọ ayọ t'o le dun ju, Ayọ t'ayé. Odigbose, ara, N'ifẹ at' igbagbọ, Tit'a o fi tun pade loke, N'ile wa ọrun. AMIN

Hymn 582 – ORO Alafia | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia