Hymn 553 – Egbe Seraf' ẹ w'asia | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Egbe Seraf' ẹ w'asia" (C&S Hymn #553, Yoruba). Ẹgbẹ Seraf' ẹ w'asia, Bo ti n fẹ lẹlẹ, Awa Kerub' si ti mura, Awa yoo…
Ẹgbẹ Seraf' ẹ w'asia, Bo ti n fẹ lẹlẹ, Awa Kerub' si ti mura, Awa yoo sẹgun. Nde Baba Aladura nde, Jesu lo ran Ọ, Awa ọmọ Rẹ ti mura, Awa ki yoo bẹru. Wo Satani pẹl' ogun rẹ, Maikiel fọn wọn ka; Awọn Alagbara subu, Seraf' tẹ wọn pa. Nde Baba Aladura nde, Jesu lo ran Ọ, Awa ọmọ Rẹ ti mura, Awa ki yoo bẹru. Jesu Olugbala wi pé, Emi fẹrẹ de, A si fi ayọ dahun pe, Ẹ dide asẹgun Nde Baba Aladura nde, Jesu lo ran Ọ, Awa ọmọ Rẹ ti mura, Awa ki yoo bẹru. Nigba ti ogun ba gbona, O pe, ―Ma bẹru‖ L'otọ Balogun wa Maikiel, Si fa da rẹ yọ. Nde Baba Aladura nde, Jesu lo ran Ọ, Awa ọmọ Rẹ ti mura, Awa ki yoo bẹru. Wo asia Jesu ti n fẹ, Ohun Ipe n dun; Mose yoo sẹgun gbogbo ọta Lagbara Jesu. Nde Baba Aladura nde, Jesu lo ran Ọ, Awa ọmọ Rẹ ti mura, Awa ki yoo bẹru. AMIN Nde Baba Aladura nde, Jesu lo ran Ọ, Awa ọmọ Rẹ ti mura, Awa ki yoo bẹru.
Hymn 553 – Egbe Seraf' ẹ w'asia | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia