Hymn 474 – LABE oji Oga Ogo | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "LABE oji Oga Ogo" (C&S Hymn #474, Yoruba). LABẸ oji Ọga Ogo, L'abo mi yoo ma wa lai, 'Tor' oju Rẹ ti ki togbe. N sọ mi…

Hymn 474 – LABE oji Oga Ogo | C&S Yoruba Hymnary
LABẸ oji Ọga Ogo, L'abo mi yoo ma wa lai, 'Tor' oju Rẹ ti ki togbe. N sọ mi sibẹ nigba gbogbo. Emi n gbe abe ojiji, Ti Ọba awọn Ọba, Oun fi iyẹ Rẹ bo mi, Mo sinmi labe abo re Labẹ oji Ọga Ogo, Mo bọ lọw' ẹru gbogbo; 'Tori apa Rẹ gba mi mu, Yi mi ka l'ọna gbogbo. Emi n gbe abe ojiji, Ti Ọba awọn Ọba, Oun fi iyẹ Rẹ bo mi, Mo sinmi labe abo re Labẹ oji Ọga Ogo, Ko s'ibi to le se mi, Oun n'ireti at'asa mi, Igbala, oun gbogbo mi Emi n gbe abe ojiji, Ti Ọba awọn Ọba, Oun fi iyẹ Rẹ bo mi, Mo sinmi labe abo re AMIN Emi n gbe abe ojiji, Ti Ọba awọn Ọba, Oun fi iyẹ Rẹ bo mi, Mo sinmi labe abo re

Hymn 474 – LABE oji Oga Ogo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia