Hymn 404 – IWE kan wa ti kika re | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "IWE kan wa ti kika re" (C&S Hymn #404, Yoruba). IWE kan wa ti kika rẹ, Ko soro fun eniyan, Ọgbọn ti awọn t'o ka n fẹ,…

Hymn 404 – IWE kan wa ti kika re | C&S Yoruba Hymnary
IWE kan wa ti kika rẹ, Ko soro fun eniyan, Ọgbọn ti awọn t'o ka n fẹ, Ni ọkan ti o mọ. Isẹ gbogbo t'Ọlọrun se, L'oke, n'ilẹ, n'nu wa; Wọn j'ọkan ninu iwe na, Lati f'Ọlọrun han. Imọlẹ osupa l'oke, Lat'ọdọ ọrun ni: Bẹ l'ogo Ijọ Ọlọrun, T'ọdọ Ọlọrun wa. Iwọ ti O jẹ ki a ri, Ohun t'o dara yi, Fun wa l'ọkan lati wa Ọ. K'a ri Ọ nibi gbogbo. AMIN

Hymn 404 – IWE kan wa ti kika re | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia