Hymn 374 – SO itan kan naa fun mi | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "SO itan kan naa fun mi" (C&S Hymn #374, Yoruba). SỌ itan kan naa fun mi, T'ohun ti mbẹ lọrun; Ti Jesu oun Ogo Rẹ, Ti…
SỌ itan kan naa fun mi, T'ohun ti mbẹ lọrun; Ti Jesu oun Ogo Rẹ, Ti Jesu oun 'Fẹ Rẹ. Sọ 'tan naa ye mi daju, B'o ba ti so f'ewe, Nitori emi ko l'okun, Mo si jẹ ẹlẹsẹ. Sọ 'tan naa fun mi pẹlẹ, Ki o ba le ye mi; Ti Iyanu Irapada; T'etutu fun ẹsẹ. Sọ fun mi nigba gbogbo, Nitori n ko fẹ gbagbe, Ero mi si n fẹ la ti gbọ, Orin adidun na. Sọ itan kan naa fun mi, N'igba t'O ba ri pe, Ogo asan ayé yi, Fẹ gba mi ni ọkan. Gba t'Ogo oke ọrun, Ba si ń fara han mi, Sọ 'tan kan naa fun mi pe, Krist' mu ọ larada. AMIN
Hymn 374 – SO itan kan naa fun mi | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia