Hymn 329 – B'ELESE s'owo po | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "B'ELESE s'owo po" (C&S Hymn #329, Yoruba). B'ẸLẸSẸ s'owọ pọ, Ti wọn nde s'Oluwa, Dimọ si Kristi Rẹ, Lati gan Ọba na,…

Hymn 329 – B'ELESE s'owo po | C&S Yoruba Hymnary
B'ẸLẸSẸ s'owọ pọ, Ti wọn nde s'Oluwa, Dimọ si Kristi Rẹ, Lati gan Ọba na, B'ayé n sata, Pẹlu Esu, eke ni wọn, Wọn n se lasan. Olugbala jọba! Lori oke Sion, Asẹ ti Oluwa, Gbe ọmọ Tirẹ ro: Lati 'boji, O ni, k'O nde, K'O si goke, K'O gba ni la. F'ẹru sin Oluwa, Si bọwọ f'asẹ Rẹ; F'ayọ wa sọdọ Rẹ, F'iwariri duro; p Ẹ kunlẹ fun, K'ẹ tẹriba: Sọ t'ipa Rẹ, Ki ọmọ na. AMIN

Hymn 329 – B'ELESE s'owo po | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia