Hymn 302 – EYIN ti n koja | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "EYIN ti n koja" (C&S Hymn #302, Yoruba). ẸYIN ti n kọja, Ya sọdọ Jesu p O sa san fun yin bi, pe Ki Jesu ku? Alafia…
ẸYIN ti n kọja, Ya sọdọ Jesu p O sa san fun yin bi, pe Ki Jesu ku? Alafia yin, Onigbọwọ yin, Wa wo b'ibanujẹ kan ri bayi ri? Oluwa, n'jo na, N' ibinu Rẹ gbe, Ẹsẹ yin l'Ọdaguntan, O ko wọn lọ. p O ku, k'O setu, Nitor' ẹsẹ yin; Baba sẹ ọmọ Rẹ n'isẹ 'tori yin. p K'a gb' ore-ọfẹ, Irapada mu? Fun Ẹni to jiya t'O ku nipo wa. Nigba t'aye ba pin, Awa o ma bọ; Ifẹ titobi naa, ti ki tan lailai. AMIN
Hymn 302 – EYIN ti n koja | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia