Hymn 292 – Krist' t'agbelegbu l'orin wa | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Krist' t'agbelegbu l'orin wa" (C&S Hymn #292, Yoruba). Krist' t'agbelegbu l'orin wa, Ijinlẹ t'awa n sọ; O j'ẹgan loju…

Hymn 292 – Krist' t'agbelegbu l'orin wa | C&S Yoruba Hymnary
Krist' t'agbelegbu l'orin wa, Ijinlẹ t'awa n sọ; O j'ẹgan loju awọn ju, Were lọwọ Griki. Sugbọn ọkan t'Ọlọrun kọ, F'ayọ gba ọrọ naa; Wọn ri ọgbọn, ipa ifẹ, T'o han n'Oluwa wọn. Adun, orukọ Rẹ yiye, Mu 'sọji s'ọkan wọn, Aigbagbọ l'ohun t'o ba ni jẹ Si ẹbi at'iku. Lai j'ọlọrun t'or'ọfẹ ka Bi ọwara ojo; Lasan l'Apollo funrugbin, Paul si le gbin lasan. AMIN

Hymn 292 – Krist' t'agbelegbu l'orin wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia