Hymn 290 – TANI le so t'ayọ ti mbẹ | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "TANI le so t'ayọ ti mbẹ" (C&S Hymn #290, Yoruba). TANI le so t'ayọ ti mbẹ, Ni agbala Paradise; Gba t'amusua ba pada,…

Hymn 290 – TANI le so t'ayọ ti mbẹ | C&S Yoruba Hymnary
TANI le so t'ayọ ti mbẹ, Ni agbala Paradise; Gba t'amusua ba pada, T'o si di arole ago? Ni ayọ ni Baba fi wo, Ẹ sọ ifẹ Rẹ ailopin; L'ayọ l'ọmọ wolẹ t'O ri, Ere iwaya-ija Rẹ. Tayọtayọ l'Emi sin ọ, Ọkan mimọ t'o n sọ dọtun, Awọn mimọ at'Angẹli n kọ, Orin igbala Ọba wọn. AMIN

Hymn 290 – TANI le so t'ayọ ti mbẹ | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia