Hymn 280 – BABA alanu t'o fe wa | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "BABA alanu t'o fe wa" (C&S Hymn #280, Yoruba). 1. BABA alanu t'o fẹ wa, Mo gb'ọkan mi si Ọ; pa Rẹ t'o pọ l'o gba wa;…

Hymn 280 – BABA alanu t'o fe wa | C&S Yoruba Hymnary
1. BABA alanu t'o fẹ wa, Mo gb'ọkan mi si Ọ; pa Rẹ t'o pọ l'o gba wa; Awa ń kọrin si Ọ. 2. Tirẹ papa l'awa fe se, Gb'ọkan wa fun ẹbọ; O da wa, o si tun wa bi, A f'ara wa fun Ọ. 3. Ẹmi Mimọ, wa sọdọ mi, F'ifẹ Oluwa han; Fun mi k'emi k'o le ma rin, N'ifẹ Oluwa mi. AMIN

Hymn 280 – BABA alanu t'o fe wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia