Hymn 276 – Jesu yoo jọba ni gbogbo | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Jesu yoo jọba ni gbogbo" (C&S Hymn #276, Yoruba). 1. Jesu yoo jọba ni gbogbo Ibi t'a ba le ri orun; 'Jọba Rẹ yo tan…

Hymn 276 – Jesu yoo jọba ni gbogbo | C&S Yoruba Hymnary
1. Jesu yoo jọba ni gbogbo Ibi t'a ba le ri orun; 'Jọba Rẹ yo tan kakiri, 'Jọba Rẹ ki y'o nipẹkun. 2. Oun l'a o ma gbadura si, Awọn Ọba yoo pe l'Ọba; Orukọ Rẹ b'orun didun, Y'o ba ẹbọ oorọ goke. 3. Gbogbo oniruru ede, Y'o fi 'fẹ Rẹ kọrin didun, p Awọn ọmọde o jẹwọ, Pe, 'bukun wọn t'ọdọ Rẹ wa. 4. 'Bukun pọ nibi t'Oun jọba; A tu awọn onde silẹ, Awọn alarẹ ri isinmi; Alaini si ri 'bukun gba. 5. Ki gbogbo ẹda k'o dide, Ki wọn f'ọla fun Ọba wa; K'Angel' tun wa t'awọn t'orin, Ki gbogb' ayé jumọ gberin. AMIN

Hymn 276 – Jesu yoo jọba ni gbogbo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia