Hymn 248 – Jesu mi, mu mi gb' ohun Re | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Jesu mi, mu mi gb' ohun Re" (C&S Hymn #248, Yoruba). 1. Jesu mi, mu mi gb' ohun Rẹ S'ọrọ alafia; Gbogbo ipa mi y'o…

Hymn 248 – Jesu mi, mu mi gb' ohun Re | C&S Yoruba Hymnary
1. Jesu mi, mu mi gb' ohun Rẹ S'ọrọ alafia; Gbogbo ipa mi y'o dalu Lati yin ore Rẹ. 2. Fi iyọnu pe mi l'ọmọ, K'o si dariji mi; Ohun na yoo dun mọ mi, B'iro orin ọrun. 3. Ibikibi t'o tọ mi si, L'emi o f'ayọ lọ; Tayọtayọ l'emi o si Dapọ m'awọn oku. 4. 'Gba ẹru ẹbi ba kọja, Ẹru mi ko si mọ, Ọwọ t'o fun 'dariji ka, Y' o pin ade iye. AMIN

Hymn 248 – Jesu mi, mu mi gb' ohun Re | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia