Hymn 204 – AYO b'aye! Oluwa de | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "AYO b'aye! Oluwa de" (C&S Hymn #204, Yoruba). 1. AYỌ b'ayé! Oluwa de; K'ayé gba Ọba re; Ki gbogbo ọkan mura de, K'ayé…

Hymn 204 – AYO b'aye! Oluwa de | C&S Yoruba Hymnary
1. AYỌ b'ayé! Oluwa de; K'ayé gba Ọba re; Ki gbogbo ọkan mura de, K'ayé kọrin soke. 2. Ayọ b'ayé! Jesu jọba, Ẹ jẹ k'a ho f'ayọ: Gbogbo igbe, omi, oke, Wọn ń gberin ayọ naa. 3. K'ẹsẹ oun 'yọnu pin l'ayé, K'ẹgun ye hu n'ilẹ; O de lati mu 'bukun san, De'bi t'ẹgun gbe de. 4. O f'otọ at'ifẹ jỌba, O jẹ k'oril' ede, Mọ ododo ijọba Rẹ, At'ifẹ 'yọnu Rẹ. AMIN

Hymn 204 – AYO b'aye! Oluwa de | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia