Hymn 189 – ARA mi fun 'rugbin rere | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "ARA mi fun 'rugbin rere" (C&S Hymn #189, Yoruba). 1. ARA mi fun 'rugbin rere, Nigba ifunrugbin wa, Ma sisẹ l'orukọ…

Hymn 189 – ARA mi fun 'rugbin rere | C&S Yoruba Hymnary
1. ARA mi fun 'rugbin rere, Nigba ifunrugbin wa, Ma sisẹ l'orukọ Jesu, Tit' Oun o tun pada wa. Nigba naa ni a o f'ayọ) ka a )2ce Olukore a ko wọn ) si aba ) 2. Olugbala pase wi pé, ―Sisẹ nigba t'o j'ọsan; Oru mbọ wa,‖ mura giri, Oloko fere de na. 3. T'agba t'ewe jumọ ke pe, 'Wọ l'Oluranlọwọ wa; Mu ni funrugbin igbagbọ, K'a s'eso itẹwọgba. 4. mf Lala isẹ fẹrẹ d'opin, Ọwọ wa fẹ ba ere; B'o de ninu ọla nla Re, Y'o sọ fun wa pe, ―Siwọ Nigba naa ni a o f'ayọ) ka a )2ce Olukore a ko wọn ) si aba ) AMIN

Hymn 189 – ARA mi fun 'rugbin rere | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia