Hymn 940 – OLORUN, ‘ranwo eni Re | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "OLORUN, ‘ranwo eni Re" (C&S Hymn #940, Yoruba). 1. OLORUN, ‘ranwo eni Re Reti wa n‘igba bi A gba ‘Wo Eni Airi gbo Awa…

Hymn 940 – OLORUN, ‘ranwo eni Re | C&S Yoruba Hymnary
1. OLORUN, ‘ranwo eni Re Reti wa n‘igba bi A gba ‘Wo Eni Airi gbo Awa nwa O sibe. 2. Ese ti awon elese Nfojudi ipa Re Ti won si nhale b'enipe ‘Wo ko ri ese won. 3. Oluwa, dide k'o gba wa A m'oran wa t'O wa F‘ododo at'ipa joba Wo nikan Ii Oba. 4. Iwo mo gbogbo ife wa ‘Ranwo Re wa n‘tosi Pese okan wa f'adura Si gba adura wa. Amin

Hymn 940 – OLORUN, ‘ranwo eni Re | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia