Hymn 924 – AWA f’ori bale fun/O Jesu | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "AWA f’ori bale fun/O Jesu" (C&S Hymn #924, Yoruba). 1. AWA f’ori bale fun/O Jesu Wo ti s’Olori ljo awon/eniyan Re Ijo…

Hymn 924 – AWA f’ori bale fun/O Jesu | C&S Yoruba Hymnary
1. AWA f’ori bale fun/O Jesu Wo ti s’Olori ljo awon/eniyan Re Ijo ti mbe laye yi ati lo/run pelu Ale/luya. 2. Wo t‘oku, t‘o si jin/de fun wa T’o mbe lodo Baba bi Ala/gbawi wa K‘ogo atolanlan/je Tire Ale/luya. 3. Ati li ojo nla Pen/tikosi Ti o ran Paraklitj/si aye Olutunu nla Re ti/mba wa gbe Ale/luya. 4. Lat’ori ite Re l’ok/ke orun L'o o si nwo gbogbo awon o/jise Re T'o si nsike gbogbo awon Aje/riku Re Ale/luya. 5. A fi iyin at'olanlan f’o/ruko Re N'tori iku gbogbo awon o/jise Re Ni gbogbo ile, Yo/ruba yi Ale/luya. Amin

Hymn 924 – AWA f’ori bale fun/O Jesu | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia