Hymn 922 – OLORUN Oluwa l'oba | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "OLORUN Oluwa l'oba" (C&S Hymn #922, Yoruba). 1. OLORUN Oluwa l'oba Aye mbe niwaju Re Nibi t’awon angel nsin I L’O…
1. OLORUN Oluwa l'oba Aye mbe niwaju Re Nibi t’awon angel nsin I L’O gunwa ni ite Re Eni Mimo Obangiji, On l'Oba. 2. Oba Ogo Ii Olorun Sion royin Re k‘aye lsra-eli ti igbani Kede itan oto Re Eni Mimo Mimo li oruko Re. 3. Li atijo, ni ‘gba ewu T’awon ojise Re be O gbo gbe awon eniyan Re N'nu eru won, O dahun Eni Mimo Won ri n'tosi gba won p'e. 4. Awon l‘afun l’ofin mimo Lat' inu awosanma Ilana mimo ti won ru Mu ki O binu si won Eni Mimo Won kanu fun ese won. 5. Sugbon Baba won fiji won Gba won tun safari Re O mura tan lati gba won O f‘ife gba won pada Eni Mimo Awa na nw’or'ofe Re. 6. Baba wa n’iyonu n'nu Kristi Y‘o mu ileri Re se Wa, k‘a gbe ga, gbogbo'alaye E wa soke mimo Re! Eni Mimo E sin loke mimo Re. Amin
Hymn 922 – OLORUN Oluwa l'oba | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia