Hymn 920 – GBO ohun Jesu ti nke pe | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "GBO ohun Jesu ti nke pe" (C&S Hymn #920, Yoruba). 1. GBO ohun Jesu ti nke pe Tani y‘o sise loni Oko pon pupo fun ‘kore…
1. GBO ohun Jesu ti nke pe Tani y‘o sise loni Oko pon pupo fun ‘kore Tani y’o lo ko wa l’e Kikan kikan l’Oluwa npe Ebun nla ni y’O fun o Tani y’o fl ayo dahun Pe” Emi ni yi ran mi? 2. B’iwo ko le okun lo Lati w’awon keferi O le ri won nitosi re Nwon wa l’enu ona B’o ko le fi wura tore Ebun miran ko kere Die t’o sise fun Jesu ‘Yebiye ni l'oju Re. 3. B’iwo ko le se alore L‘ori odi Sioni Lati t’oka s’ona orun Lati f’iye lo eda Wole f'adura at’ore Se ohun t’Olorun wi Wo le se gegebi Aaron T’o gbowo woli soke. 4. Ma je k’a gbo ki o wipe Ko si nkan t’emi le se Nigbat’ emi eniyan nku Ti Oluwa si npe o F’ayo gba ise t’O ran o, Fise Re se ayo re Gbat’ o npe o, tara dahun Pe emi ni yi, ran mi. Amin
Hymn 920 – GBO ohun Jesu ti nke pe | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia