Hymn xxxvii – Gba mi Baba gba mi dakun ye | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Gba mi Baba gba mi dakun ye" (C&S Hymn #xxxvii, Yoruba). Gba mi Baba gba mi dakun ye, ) Gba mi Baba gba mi dakun, )…

Hymn xxxvii – Gba mi Baba gba mi dakun ye | C&S Yoruba Hymnary
Gba mi Baba gba mi dakun ye, ) Gba mi Baba gba mi dakun, ) 2ce Ọgbagba ti n gba gbogbo ẹlẹsẹ, )2ce Iwọ nikan sa ni mo d'ẹsẹ si Baba, Gba mi Baba gba mi dakun ye, Gba mi Baba gba mi dakun. Mo de Baba gba mi dakun ye ) Mo de Baba gba mi dakun ) 2ce Ọmọ oninakuna de mo de, )2ce Emi ko tun r'ẹni sa tọ mọ ye Baba, Iwọ l'apata Igbala mi, Mo de Baba gba mi dakun. ASẸ

Hymn xxxvii – Gba mi Baba gba mi dakun ye | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia