Hymn 879 – F'ORUK' Olorun loke | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "F'ORUK' Olorun loke" (C&S Hymn #879, Yoruba). 1. F'ORUK' Olorun loke T’O l'agbara at’ola Olorun ibi gbogbo N'iyin ati…

Hymn 879 – F'ORUK' Olorun loke | C&S Yoruba Hymnary
1. F'ORUK' Olorun loke T’O l'agbara at’ola Olorun ibi gbogbo N'iyin ati ogo wa 2. F‘oruko Krist’ Oluwa Om’ Olorun ti a bi Krist’ t’O da ohun gbogbo Ni k'a san ‘yin ailopin. 3. F'Olorun Emi Mimo Ni k’iyin pipe wa lae Pelu baba at’Omo Okan l’oruko, l’ogo. 4. Orin t'a ti ko koja T’ao si ma ko lae leyi Ki awon iran ti mbo Dapo korin didun na. Amin

Hymn 879 – F'ORUK' Olorun loke | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia