Hymn x – Jehovah mi si wa lojo oni Baba | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Jehovah mi si wa lojo oni Baba" (C&S Hymn #x, Yoruba). Jehovah mi si wa lọjọ oni Baba, A wolẹ fun Ọ! wa, wa, wa, Ẹmi…
Jehovah mi si wa lọjọ oni Baba, A wolẹ fun Ọ! wa, wa, wa, Ẹmi Ọrun jare wa mi si wa loni o o o e, Jọwọ ye, gba wa o! Lọwọ aye, lọwọ ọta, lọwọ iku ojiji, Tẹmbẹlẹkun ọmọ araye gbawa o ! A dupẹ Edumare: Jehovah mi si wa l'ọjọ oni Baba A kunlẹ fun Ọ o wa, wa, wa, Ẹmi ọrun jare wa mi si wa, Loni o o o e. ASẸ, AMIN O, KO SẸ
Hymn x – Jehovah mi si wa lojo oni Baba | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia