Hymn viii – Jeki 'sin wa oni le je 'tewogba o | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Jeki 'sin wa oni le je 'tewogba o" (C&S Hymn #viii, Yoruba). Jẹki 'sin wa oni le jẹ 'tẹwọgba o, Bukun 'sin wa oni, Wa…

Hymn viii – Jeki 'sin wa oni le je 'tewogba o | C&S Yoruba Hymnary
Jẹki 'sin wa oni le jẹ 'tẹwọgba o, Bukun 'sin wa oni, Wa fun wa layọ. Fun wa l'Ẹmi re, )2ce Fun wa l'Ẹmi Rẹ o Baba, Ka le jẹ tirẹ. Dari ẹsẹ wa ji wa loni Baba, Bukun 'sin wa oni — Wa fun wa layọ. Fun wa l'Ẹmi re, )2ce Fun wa l'Ẹmi Rẹ o Baba, Ka le jẹ tirẹ. Gba'yin gb'ore wa t'a mu wa fun Ọ o, Wa mi si wa Baba — ka mayọ rele. Fun wa l'Ẹmi re, )2ce Fun wa l'Ẹmi Rẹ o Baba, Ka le jẹ tirẹ. ASẸ Fun wa l'Ẹmi re, )2ce Fun wa l'Ẹmi Rẹ o Baba, Ka le jẹ tirẹ.

Hymn viii – Jeki 'sin wa oni le je 'tewogba o | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia