Hymn vi – Baba Olodumare a tun de | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Baba Olodumare a tun de" (C&S Hymn #vi, Yoruba). Baba Olodumare a tún de, ) Olu Ọrun o - awa ma tun de, )2ce Ọba to n…
Baba Olodumare a tún de, ) Olu Ọrun o - awa ma tun de, )2ce Ọba to n so ohun gbogbo Ọba to n s'ohun gbogbo Ọba to da wa si latesi, Ọba to n pa wa mọ, Ọba to n pese fun wa, Ipese alafia to ju ohun gbogbo lọ, Ọba ikẹ Igẹ, A m'ọrẹ wa fun Ọ o — Ọba Eledumare, Ye - Wa gb'ore wa o, Baba Mimọ. ASẸ
Hymn vi – Baba Olodumare a tun de | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia