Hymn ii – Emi, Emi, l'Olorun awon to ba n sin O o | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Emi, Emi, l'Olorun awon to ba n sin O o" (C&S Hymn #ii, Yoruba). Ẹmi, Ẹmi, l'Ọlọrun awọn to ba n sin Ọ o, 2ce Ẹmi pẹlu…

Hymn ii – Emi, Emi, l'Olorun awon to ba n sin O o | C&S Yoruba Hymnary
Ẹmi, Ẹmi, l'Ọlọrun awọn to ba n sin Ọ o, 2ce Ẹmi pẹlu otitọ ni ki wọn kunlẹ, Iwọ to n gbe arin awọn Kérúbù, Jọwọ sunmọ wa Baba. ASẸ, AMIN O! KO SẸ

Hymn ii – Emi, Emi, l'Olorun awon to ba n sin O o | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia