Hymn 620 – EMI Olorun wa | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "EMI Olorun wa" (C&S Hymn #620, Yoruba). ẸMI Ọlọrun wa, Baptis' awọn wọnyi, Ba wọn da majẹmu mimọ, Wẹ wọn kuro l'ẹsẹ.…
ẸMI Ọlọrun wa, Baptis' awọn wọnyi, Ba wọn da majẹmu mimọ, Wẹ wọn kuro l'ẹsẹ. F'ọpa esu tutu, Wẹ wọn n'nu ẹjẹ Rẹ; Baba, Ọmọ, Ẹmi Mimọ , Sọ wọn di ọmọ Rẹ. AMIN
Hymn 620 – EMI Olorun wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia