Hymn 606 – GBE 'banuje re mi, o kari aye | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "GBE 'banuje re mi, o kari aye" (C&S Hymn #606, Yoruba). GBE 'banujẹ rẹ mi, o kari ayé, Fi s'ohun igbagbe, rọju pa…

Hymn 606 – GBE 'banuje re mi, o kari aye | C&S Yoruba Hymnary
GBE 'banujẹ rẹ mi, o kari ayé, Fi s'ohun igbagbe, rọju pa mọra; Fi suru ronu rẹ/ni oru 'ganjọ 'Tọ Jesu lọ ro fun/yoo si san fun Ọ. Tọ Jesu lọ, ro fun, O mọ ẹdun rẹ, Tọ Jesu lọ, ro fun, yoo ran ọ lọwọ; Lo jẹ k'adun ayọ/to pese fun Ọ, Yoo m'eru rẹ fuyẹ/sa lọ gbadura. Awọn ti osi wọn/pọ ju tirẹ lọ, N' sori kọ n'nu okun, lo tu wọn ninu; Gbe 'banujẹ rẹ mi, f'ẹlomi layọ; Lo tan 'mọlẹ fun wọn/f'abọ fun Jesu. AMIN

Hymn 606 – GBE 'banuje re mi, o kari aye | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia