Hymn 050 – BABA Oludariji | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "BABA Oludariji" (C&S Hymn #050, Yoruba). 1. BABA Oludariji Dariji, Gbogbo awa ọmọ Rẹ, Dariji, Awa Ẹgbẹ Séráfù, Ati…
1. BABA Oludariji Dariji, Gbogbo awa ọmọ Rẹ, Dariji, Awa Ẹgbẹ Séráfù, Ati Ẹgbẹ Kérúbù, Ati n pafọ ninu ẹsẹ, Dariji 2. JESU OLUGBALA WA Dariji, OLURAPADA Ẹda Dariji, Wọ to mbẹbẹ f'ọta Rẹ L'origi Agbelebu Wi pé fi ji wọn BABA Dariji. 3. ẸMI OLUTUNU wa, Dariji, Gbogbo ẹbi ẹsẹ wa, Dariji, Gba wa lọjọ idamu Se Oluranlọwọ wa, Mase jẹ ki a bọhun Dariji. 4. MẸTALỌKAN jọwọ wa Dariji, Ọmọde ati Agba, Dariji, JAH JEHOVAH RAMMAH 'Wọ l'Ọba Oniyọnu, Dariji 'sẹ ọwọ Rẹ, Dariji. AMIN
Hymn 050 – BABA Oludariji | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia