Hymn 472 – Tire lailai l'awa se | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Tire lailai l'awa se" (C&S Hymn #472, Yoruba). Tirẹ lailai l'awa se, Baba, Ọlọrun ife; Jẹ ka jẹ Tirẹ titi, Layé yi,…
Tirẹ lailai l'awa se, Baba, Ọlọrun ife; Jẹ ka jẹ Tirẹ titi, Layé yi, ati lailai. Tirẹ lailai l'awa se, Ma toju wa l' ayé yi; 'Wọ iye, ọna otọ, To wa si ilu ọrun. Tirẹ lailai:- Abukun L'awọn t'o se 'sinmi wọn! Olugbala, Ọrẹ wa, Gba 'ja wa ja de opin. Tirẹ lailai: - Jesu, pa Awọn aguntan Rẹ mọ, Labẹ isọ rere Rẹ, Ni k'o pa gbogbo wa mọ. Tirẹ lailai: - Aini wa, Ni o je aniyan Rẹ; O ti f'ẹsẹ wa ji wa, Tọ wa si ibugbe Rẹ. AMIN
Hymn 472 – Tire lailai l'awa se | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia