Hymn 465 – Nihin l'ayida wa | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Nihin l'ayida wa" (C&S Hymn #465, Yoruba). Nihin l'ayida wa; Ojo, ẹrun, n kọja, di Ilẹ ni ń yan, ti o si ń sa, 'Tana…
Nihin l'ayida wa; Ojo, ẹrun, n kọja, di Ilẹ ni ń yan, ti o si ń sa, 'Tana dada si n ku: Sugbọn ọrọ Jesu duro, N ó wa pẹlu rẹ,‖ ni Oun wi. Nihin l'ayida wa, L'ona ajo ọrun; N'nu 'gbagbọ, 'reti, at'ẹru, N'nu 'fẹ s'Ọlọrun wa; A ń saika ọrọ yi si po! N ó wa pẹlu ẹ.‖ ni Oun wi. Nihin l'ayida wa; Sugbọn l'a rin eyi, L'arin ayidayid' ayé; Ọkan wa ti ki yi; Ọrọ Jehofa ki pada; N ó wa pẹlu rẹ,‖ ni Oun wi. Ọna alafia: Immanueli wa; Majẹmu ti ore ọfẹ, Lai wọn ki yipada; 'Nki yipada‖ l'ọrọ Baba, Mo wa pẹlu rẹ,‖ ni Oun wi. AMIN
Hymn 465 – Nihin l'ayida wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia