Hymn 428 – SA wo ite anu | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "SA wo ite anu" (C&S Hymn #428, Yoruba). SA wo itẹ anu! Ọrọ Rẹ pe mi wa , Nibẹ Jesu f'oju rẹ han, Lati gbọ adura. Ẹjẹ…

Hymn 428 – SA wo ite anu | C&S Yoruba Hymnary
SA wo itẹ anu! Ọrọ Rẹ pe mi wa , Nibẹ Jesu f'oju rẹ han, Lati gbọ adura. Ẹjẹ etutu ni, Ti a ti ta silẹ; Pese ẹbẹ t'o le bori, F'awọn t'o n t'Ọlọrun. Ifẹ Rẹ le fun mi, Ju bi mo ti fẹ lọ; A ma fun ẹni t'o bere, Ju bi wọn ti n fẹ lọ. Fun wa l'aworan Rẹ, At'oju rere Rẹ; Jẹ ki n le sin Ọ nihin yii Ki mba le ba Ọ gbe. AMIN

Hymn 428 – SA wo ite anu | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia