God's Glory Album - Wa Ro Jo O — Seraphmedia
A 9-minute C&S album track by Seraphmedia from God's Glory Album - C&S Ayo-ni-o. Listen to “God's Glory Album - Wa Ro Jo O” or download it free on Seraphmedia.
Gbogbo ise wa ti a n se, gbogbo iwa ti a n wu, gbogbo oro wa ti a n so, e je ka ma sora. Nitori Oluwa yo mu gbogbo ise wa si idajo, ati gbogbo ohun ti a bi, ire tabi ibi. Wa ro jo o, wa duro pe. Wa ro jo o, wa duro pe. Lenu bode orun o lati jihin ohun gbogbo to se ninu aye se. Wa ro jo o, wa duro pe. Wa ro jo se, wa duro pe. Lenu bode orun o lati jihin ohun gbogbo to se ninu aye se. Ajo ma nile aye je o, e ma se waye ma ya. Ajo ma nile aye je o, e ma se waye ma ya. Rere ti a ba se ninu re, gedere ma ni loju Oluwa. Ibi ti a ba se ninu re, gedere ma ni loju Oluwa. Wa ro jo o, wa duro pe. O daju wa ro jo se, wa duro pe. Lenu bode orun o lati jihin ohun gbogbo to se ninu aye se. Ma se gbagbe oba to da o. To tun na o jiji pelu re. Bi bi di o lati record ohun gbogbo to se ninu aye, yala ni rere tabi buburu. Bi gun ba de to ma de inu bode, a o fun won ni playback e, ise re to se ninu aye. Wa ro jo o, wa duro pe. Wa ro jo se, wa duro pe. Lenu bode orun o lati jihin ohun gbogbo to se ninu aye se. Awa wi kan ko ma ni si mo, tori ko ni si boju mo. Awa wi kan ko ma ni si o, tori ko ni si boju mo. You cannot say I beg you sir, idajo lo ku to ma doju ko. You cannot say I am sorry sir, judgment lo ma doju ko. A ku wo ku se ohun re, a ku wo ko ri inu re. Yala lati lo si owo otun, to ku fun ayo o, to ku fun iyin o. Tabi lati lo si owo osi, to ku fun irora fun ipa yin gege. Wa ro jo o, wa duro pe. O daju wa ro jo se, wa duro pe. Lenu bode orun o lati jihin ohun gbogbo to se ninu aye se. Oluwa n bo aye yo mi, o de tan. Jesu Kristi n bo la wa san mo, o de tan. Oluwa n bo aye yo mi se, o de tan. Jesu Kristi n bo la wa san mo, o de tan. Awon oke yi o si di ni ipo won, irawo oju orun yo mu mole won kuro. Nide Jesu, sun mo eti le o. Eyin ayanfe, e mura sile. Oku fun yo koja o, imole yo farahan. Lojo idajo, ojo mimo oloko. Nide Jesu, sun mo eti le o. Eyin ayanfe, e mura sile. O ni idajo aye n bo, enke yo pa lorun o. Ile aye yo su o, torun yo si mo keje re. Nide Jesu, sun mo eti le o. Eyin ayanfe, e mura sile. Eni to ba segun o, ni yo de ni irapada. Ohun yo gba de ogo, ataso gbo wiwe. Nide Jesu, sun mo eti le o. Eyin ayanfe, e mura sile. Ta ni fe lo lati ba Jesu joba? Emi fe lo. Ta ni fe lo lati ba angeli korin? Emi fe lo. To ba fe lo, yora yin pada. Ore to ba fe lo o, yora yin pada kuro ninu ibi o, iwa eri gbogbo. Tori lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. Iwo lo ma daduro o, iwo lo ma daduro. Lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. Iwo lo ma daduro o, iwo lo ma daduro. Lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. Iwo lo ma daduro o, iwo lo ma daduro. Lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. Ni le mimo oloko, ti je paradise, lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. Agbejo ro ko ni si o, niwaju oga ogo. Lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. Ise ro n be fun ise re to se laye ese yi. Lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. Ipe o ba ti dun o, Jesu lo be be fun wa. Lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. O ni daduro, daduro eniyan bi n be ninu won o. Lojo ikeyin, iwo lo ma daduro. Yowon ronu ti Olorun ma da, a gbojo ikeyin to de. Olorun ma da, a gbojo ikeyin to de. Olorun ma da, a gbojo ikeyin to de. Olorun ma da, a gbojo ikeyin to de.