God's Glory Album - Bi Awon Eniyan Mi — Seraphmedia

“God's Glory Album - Bi Awon Eniyan Mi” — a 7-minute C&S album track by Seraphmedia from God's Glory Album - C&S Ayo-ni-o. Free to stream or download on…

God's Glory Album - Bi Awon Eniyan Mi — Seraphmedia
Iya won eni omi, ti a n fi oruko mi pe, o ba re ara won sile, ti won si gbadura. Ti won ba si wa oju mi, ti won ba si yi pada kuro ninu ona buruku won, emi a gbo lati orun wa, emi a dari ese won ji, emi a wo ile won san. Iya won eni omi, ti a n fi oruko mi pe, o ba re ara won sile, ti won si gbadura. Ti won ba si wa oju mi, ti won ba si yi pada kuro ninu ona buruku won, emi a gbo lati orun wa, emi a dari ese won ji, emi a wo ile won san. Iya yi ti to, omo eniyan, sa tolorun lo. Ibanuje ti to, omo eniyan, sa tolorun lo. A ko le wa ninu ese, ka ni ko re o, be ko si. Eni bo ese re mole, o daju, ki o se rere. Ojo wo ni oro yi yo se si o lara, ti a o pe o ni eni iwari, yo wa ikosile. Iya won eni omi, ti a n fi oruko mi pe, o ba re ara won sile, ti won si gbadura. Ti won ba si wa oju mi, ti won ba si yi pada kuro ninu ona buruku won, emi a gbo lati orun wa, emi a dari ese won ji, emi a wo ile won san. Ibi anu n gbo le je, meya lu n be, feniyan, orisun to san fe je. Alisawotan ese wa, mi ti ju la je wo ese, oju anu wa. Iya won eni omi, ti a n fi oruko mi pe, o ba re ara won sile, ti won si gbadura. Ti won ba si wa oju mi, ti won ba si yi pada kuro ninu ona buruku won, emi a gbo lati orun wa, emi a dari ese won ji, emi a wo ile won san. Malumolu wa re, petekete mo ibu joko re. Malumolu wa re o, petekete mo ibu joko re. Israeli ko mo mi, awon eni omi ko ronu. A nu se mi, Israeli ko mo mi o, awon eni omi ko ronu. Si ko, alaanu lo luwa, won ba ti ko fe iku ese. Bi ese re kon bi alare, won fun fun mi egbo. Iki le je Jesu, o ti to fun ra pada re. Eje kiki, eje Jesu, o ti to fun ra pada re. Oluwa, Olorun awon omo ogun, tani alagbara bi iwo? Oluwa, Olorun awon omo ogun, tani alagbara bi iwo? Gbogbo okan to to wa, o ni o ki o ta mo ni. Ore, si mi le Jesu, o daju yo ra o pada, si mi le. Si mi le Jesu, faramo, faramo Jesu, sun mo o. Si mi le Jesu, faramo, yo se ti re lasiko. Si mi le Jesu, faramo, faramo Jesu, sun mo o. Si mi le Jesu, faramo, yo se ti re lasiko. Gegele o ni gbagbo, bi isoro ba de, yo mu o na ja. Si mi le Jesu, faramo, faramo Jesu, sun mo o. Si mi le Jesu, faramo, yo se ti re lasiko. Ranti, o di ye lo mu, ranti, o di ye lo mu. Si mi le Jesu, faramo, faramo Jesu, sun mo o. Si mi le Jesu, faramo, yo se ti re lasiko. Si mi le, si mi le, si mi le, eh, eh, eh, ohun lo le gba o. Si mi le Jesu, faramo, faramo Jesu, sun mo o. Si mi le Jesu, faramo, yo se ti re lasiko.

God's Glory Album - Bi Awon Eniyan Mi — Seraphmedia on Seraphmedia