ASIRI ADURA - Ejire Aditu Ogo — Ejire Aditu Ogo
A spoken word message in Yoruba and English encouraging persistence in prayer and gratitude, illustrated by a parable of a farmer and the value of wisdom.
Aṣiri adura. To fi le bere, you have been asking God for many things. It seems things are just the same. Okay, this is what you are going to do. Wisdom is better than silver and gold. Daddy, if you have wisdom, you will get more than silver and gold. Now, if you lose wisdom, you will lack both silver and gold. Wisdom is better than silver and gold. Agbẹ yi lo lo pe Baba Joseph, ayo Baba Lolalẹ. Baba ẹ jọ, oko awọn o ti ẹ hu nkankan. People's farm is, you know, it has been bringing good things. Ṣugbọn Baba, oko ohun o yọ nkankan. O n ti gbadura, ẹ wa ba ohun gbadura s'oko yi. The way you have been praying to God, Oluwa mo fẹ ko ṣe. Ẹmi ma mo fẹ ko ṣe. Ah, ohun to ma ṣe re. Baba Joseph, ayo Baba Lolalẹ, wọn wa do'nu oko. Nigba ti mo lọ s'ori oke, ti wọn n pe ni Power House abi? Power House, ẹ ṣe. Nibi ti wọn si n Baba Joseph, ayo Baba Lolalẹ si, awọn ojiṣẹ Ọlọrun lo n sọ. Ẹ dẹ mọ pe olorin olofoofo ni wa a ma sọ. Wọn ni, agbẹ yi ba ni Baba, ẹ gbadura. Baba ba de'nu oko, Baba ba wọlẹ, Baba ba kunlẹ, Baba ba wọlẹ. Wọn l'Ọlọrun o ṣe. Baba mi o ṣe. He did not say, oya ki gori ko yi, ki gbogbo ẹgbẹ ki oko to si da ma ja. No, no, no. O l'Ọlọrun o ṣe. Iwo l'Ọlọrun o ṣe. Ẹni to lọ pe Baba, o wo pe one hour ti lọ. Ah ah, kin leleyi? Two hours ti lọ. Three hours ti lọ. L'ori Ọlọrun o ṣe. Four, five, six, seven, eight hours. Ọlọrun o le duro nbi o ba lọ le. Baba si wa l'ori ikunlẹ. Kini wọn n wi? Ọlọrun o ṣe. Ẹn, o ṣe ayẹn dari. L'ọjọ keji, agbẹ ba wa pe Baba o ti gbadura tan. Ẹẹ gọ, wisdom is better than silver and gold. Nigba to d'ọjọ keji, o ba de'nu oko, Baba si tun wa l'ori ikunlẹ. Ọlọrun a lo o ṣe. Ẹmi mi mo o ṣe. Tori pe oko yi ti ṣe ṣe. Wakati kan tun lọ, wakati meji, mẹta, mẹrin, marun, o tun wo pe rara o. Ilẹ ti su, o tun lọ, o tun fi Baba si bẹ. Baba si n sọ pe Ọlọrun o ṣe. Nkan to n bẹrẹ yẹn, ọpẹ lo yẹ ko ma bẹrẹ. Ọlọrun o ma ṣe. Oko lo n wa, iṣẹ lo n wa. With faith, Ọlọrun o ṣe tori pe o ti ṣe. Don't ṣe ṣe. Sọ pe o ṣe tori pe o ti ṣe. Don't say ṣe. Ọlọrun o ṣe tori pe o ti ṣe. Don't say ṣe. Thank you. Ọjọ kẹta, agbẹ ba wa s'oko, o ba tun ba Baba l'ori ikunlẹ. A l'Ọlọrun o ṣe sẹ. Igba to ya Baba ba l'Ọlọrun o ṣe tori pe o ti gba ogbo ogo, Baba ba dide, wọn ba n lọ le. Without asking for anything. Kin lo n to n da mu ẹ? O kan need lati sọ pe Ọlọrun o ṣe. Ma sọ pe ṣe. Ọlọrun o ṣe tori pe o ti ṣe. Wọn ni ni gbogbo ilu yẹn, l'ọdun yẹn ko s'ẹni to ro ko to da to ti ẹ. L'ori pe Ọlọrun o ṣe. Ta lo wa nbi to ṣe tan lati lọ Ọlọrun o ṣe? L'ori career mi, kọju si pẹpẹ, Ọlọrun o ṣe tori pe o ti gbe iṣẹ mi ga. Iṣẹju meji kan wo, emi o mọ nkan to n disturb mind ẹ. Kan ma sọ pe Ọlọrun o ṣe. Ọlọrun mo lo o ṣe. Ati gbogbo instrumentalist, Ọlọrun o ṣe. L'ori aye mi, l'ori ministry mi, Ọlọrun o ma ṣe. Ọlọrun o ṣe. Ọlọrun o ṣe. Ọlọrun o ṣe. Awọn eeyan n dupe, Ọlọrun wọn lo o ṣe. Give thanks with a grateful heart. Give thanks to the holy one. Give thanks because he's given Jesus Christ his son. Give thanks with a grateful heart. Give thanks to the holy one. Give thanks because he's given Jesus Christ his son. And now, and now, hey, let the weak say I am strong. So, let the poor say I am rich. Thank you. Because of what the Lord has done for us. And now, let the weak say I am. Let the weak say I am strong. Let the poor say I am rich because of what the Lord has done for us. Oh, oh, oh, give thanks to the Lord. Give thanks. Everybody give thanks to him. Give thanks. Ma dupe ore to ṣe fun ọ. Give thanks. Everybody give thanks to him. Give thanks. Mommy, daddy, give thanks to him. Ogo akorin, give thanks to Him. Give thanks. Eyin baba mi, give thanks to Him. Give thanks. Everybody give thanks to Him. Give thanks. Mommy, na di give thanks to Him. Give thanks. Papa, na di give thanks to Him o. Give thanks. Oya, give thanks to Him. Give thanks. Mommy, give thanks to Him o. Give thanks. Daddy, o give thanks to Him. Give thanks. Oya,
ASIRI ADURA - Ejire Aditu Ogo — Ejire Aditu Ogo on Seraphmedia